Samuẹli Keji 16:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Huṣai dáhùn pé, “Ẹ̀yìn ẹnikẹ́ni tí OLUWA, ati àwọn eniyan wọnyi, ati gbogbo Israẹli bá yàn ni mo wà. Tirẹ̀ ni n óo jẹ́, n óo sì dúró tì í.

Samuẹli Keji 16

Samuẹli Keji 16:15-23