Samuẹli Keji 16:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Absalomu bá bi í pé, “Kí ló dé, tí o kò fi ṣe olótìítọ́ sí Dafidi ọ̀rẹ́ rẹ mọ́? Kí ló dé tí o kò fi bá a lọ?”

Samuẹli Keji 16

Samuẹli Keji 16:15-23