Samuẹli Keji 16:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọba ati àwọn eniyan rẹ̀ yóo fi dé ibi odò Jọdani, ó ti rẹ̀ wọ́n, nítorí náà, wọ́n sinmi níbẹ̀.

Samuẹli Keji 16

Samuẹli Keji 16:13-22