Samuẹli Keji 15:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Igba ọkunrin ni Absalomu pè, tí wọ́n sì bá a lọ láti Jerusalẹmu. Wọn kò ní èrò ibi lọ́kàn, ní tiwọn, wọn kò sì mọ ohun tí ó wà lọ́kàn Absalomu.

Samuẹli Keji 15

Samuẹli Keji 15:5-17