Samuẹli Keji 14:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sí ẹyọ ẹnìkan ní gbogbo Israẹli tí òkìkí ẹwà rẹ̀ kàn bí ti Absalomu. Kò sí àbùkù kankan rárá lára rẹ̀ bí ti í wù kó mọ, láti orí títí dé àtẹ́lẹsẹ̀ rẹ̀.

Samuẹli Keji 14

Samuẹli Keji 14:18-31