Samuẹli Keji 14:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ọba pàṣẹ pé kí Absalomu máa gbé ilé rẹ̀, nítorí pé òun kò fẹ́ rí i sójú. Nítorí náà, inú ilé Absalomu ni ó ń gbé, kò sì dé ọ̀dọ̀ ọba rárá.

Samuẹli Keji 14

Samuẹli Keji 14:19-33