Samuẹli Keji 13:9 BIBELI MIMỌ (BM)

ó sì dà á sinu àwo kan, ó gbé e fún un. Ṣugbọn Amnoni kọ̀, kò jẹ ẹ́, ó ní kí ó sọ fún gbogbo àwọn tí wọ́n wà ninu ilé kí wọ́n jáde, gbogbo wọn bá jáde.

Samuẹli Keji 13

Samuẹli Keji 13:1-11