Samuẹli Keji 13:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Amnoni bá sọ fún un pé, “Gbé e tọ̀ mí wá ninu yàrá mi, kí o sì gbé e kalẹ̀ níwájú mi.” Tamari bá gbé àkàrà náà, ó sì tọ Amnoni lọ láti gbé e kalẹ̀ níwájú rẹ̀ ninu yàrá.

Samuẹli Keji 13

Samuẹli Keji 13:2-16