Samuẹli Keji 13:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Absalomu sá lọ sọ́dọ̀ Talimai, ọmọ Amihudu, ọba Geṣuri, Dafidi sì ń ṣọ̀fọ̀ ọmọ rẹ̀ lojoojumọ.

Samuẹli Keji 13

Samuẹli Keji 13:28-39