Samuẹli Keji 13:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Kàkà bẹ́ẹ̀, Amnoni pe iranṣẹ rẹ̀ kan, ó wí fún un pé, “Mú obinrin yìí jáde kúrò níwájú mi, tì í sóde, kí o sì ti ìlẹ̀kùn mọ́ ọn.”

Samuẹli Keji 13

Samuẹli Keji 13:9-25