Samuẹli Keji 13:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Tamari dá a lóhùn pé, “Rárá, arakunrin mi, lílé tí ò ń lé mi jáde yìí burú ju ipá tí o fi bá mi lòpọ̀ lọ.”Ṣugbọn Amnoni kọ̀, kò gbọ́ tirẹ̀.

Samuẹli Keji 13

Samuẹli Keji 13:12-20