Samuẹli Keji 12:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi bá tu Batiṣeba, aya rẹ̀ ninu, ó bá a lòpọ̀, ó sì bí ọmọkunrin kan fún un. Dafidi sọ ọmọ yìí ní Solomoni. OLUWA fẹ́ràn ọmọ náà,

Samuẹli Keji 12

Samuẹli Keji 12:19-30