Samuẹli Keji 12:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nisinsinyii, ó ti kú, kí ni n óo tún máa gbààwẹ̀ sí? Ṣé mo lè jí i dìde ni? Èmi ni n óo tọ̀ ọ́ lọ, kò tún lè pada tọ̀ mí wá mọ́.”

Samuẹli Keji 12

Samuẹli Keji 12:22-26