Samuẹli Keji 12:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi bá ń gbadura sí Ọlọrun pé kí ara ọmọ náà lè yá, ó ń gbààwẹ̀, ó sì ń sùn lórí ilẹ̀ lásán ní alaalẹ́.

Samuẹli Keji 12

Samuẹli Keji 12:12-26