Samuẹli Keji 12:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Natani bá lọ sí ilé rẹ̀.OLUWA fi àìsàn ṣe ọmọ tí aya Uraya bí fún Dafidi.

Samuẹli Keji 12

Samuẹli Keji 12:12-18