Samuẹli Keji 10:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Dafidi gbọ́, ó kó gbogbo àwọn ọmọ ogun Israẹli jọ, ó la odò Jọdani kọjá lọ sí Helamu. Olukuluku àwọn ará Siria dúró ní ipò wọn, wọ́n dojú kọ Dafidi, wọ́n sì bá a jagun.

Samuẹli Keji 10

Samuẹli Keji 10:12-19