Samuẹli Keji 10:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Hadadeseri ọba, bá ranṣẹ sí àwọn ará Siria tí wọ́n wà ní ìhà ìlà oòrùn odò Yufurate, wọ́n bá wá sí Helamu. Ṣobaki tí ó jẹ́ balogun àwọn ọmọ ogun Hadadeseri, ni aṣiwaju wọn.

Samuẹli Keji 10

Samuẹli Keji 10:15-19