Sakaraya 8:15 BIBELI MIMỌ (BM)

bẹ́ẹ̀ ni mo tún pinnu nisinsinyii láti ṣe ẹ̀yin ará Jerusalẹmu ati àwọn ará ilé Juda ní rere. Nítorí náà, ẹ má bẹ̀rù.

Sakaraya 8

Sakaraya 8:11-16