Sakaraya 8:14 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA àwọn ọmọ ogun ní, “Gẹ́gẹ́ bí mo ti pinnu láti ṣe yín ní ibi nígbà tí àwọn baba yín mú mi bínú, tí n kò sì yí ìpinnu mi pada,

Sakaraya 8

Sakaraya 8:5-20