Sakaraya 7:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Bẹtẹli rán Ṣareseri ati Regemumeleki ati gbogbo àwọn eniyan wọn lọ sí ilé OLUWA; wọ́n lọ wá ojurere OLUWA,

Sakaraya 7

Sakaraya 7:1-7