Sakaraya 2:9 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo bá àwọn ọ̀tá yín jà; wọn yóo sì di ẹrú àwọn tí ń sìn wọ́n.Ẹ óo wá mọ̀ pé èmi ni OLUWA àwọn ọmọ ogun.

Sakaraya 2

Sakaraya 2:1-13