Sakaraya 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní, “Ẹ kọrin ayọ̀, kí ẹ sì jẹ́ kí inú yín máa dùn, ẹ̀yin ará Jerusalẹmu, nítorí pé mò ń bọ̀ wá máa ba yín gbé.

Sakaraya 2

Sakaraya 2:6-13