Sakaraya 10:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé mo ti fọ́n wọn kásí ààrin àwọn orílẹ̀-èdè,sibẹsibẹ, wọn yóo ranti mi lọ́nà jíjìn tí wọ́n wà.Àwọn ati àwọn ọmọ wọn yóo wà láàyè,wọn yóo sì pada wá sí ilẹ̀ wọn.

Sakaraya 10

Sakaraya 10:5-12