Sakaraya 10:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“N óo ṣẹ́wọ́ sí wọn,n óo sì kó wọn jọ sinu ilé.Mo ti rà wọ́n pada,nítorí náà wọn yóo tún pọ̀ bíi ti àtẹ̀yìnwá.

Sakaraya 10

Sakaraya 10:3-12