Rutu 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Boasi bá ṣú Rutu lópó, Rutu sì di aya rẹ̀. Nígbà tí Boasi bá a lòpọ̀, ó lóyún, ó bí ọmọkunrin kan.

Rutu 4

Rutu 4:8-21