Rutu 4:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ tí OLUWA yóo jẹ́ kí obinrin yìí bí fún ọ yóo kún ilé rẹ fọ́fọ́, bí ọmọ ti kún ilé Peresi, tí Tamari bí fún Juda.”

Rutu 4

Rutu 4:11-17