Peteru Kinni 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyí sọ yín di alábàápín ninu ìjìyà Kristi. Ẹ máa yọ̀. Nígbà tí ó bá pada dé ninu ògo rẹ̀, ayọ̀ ńlá ni ẹ óo yọ̀.

Peteru Kinni 4

Peteru Kinni 4:12-19