Peteru Kinni 4:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin olùfẹ́ mi, ẹ má jẹ́ kí ó jọ yín lójú bí wọ́n bá wa iná jó yín láti dán yín wò, bí ẹni pé ohun tí ojú kò rí rí ni ó dé.

Peteru Kinni 4

Peteru Kinni 4:7-19