Peteru Kinni 2:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé nígbà kan ẹ dàbí aguntan tí ó sọnù. Ṣugbọn nisinsinyii ẹ ti yipada sí olùṣọ́ yín ati alabojuto ọkàn yín.

Peteru Kinni 2

Peteru Kinni 2:21-25