Peteru Kinni 2:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Òun fúnrarẹ̀ ni ó ru ẹ̀ṣẹ̀ wa lórí igi, kí á baà lè kú sí ẹ̀ṣẹ̀, kí á wà láàyè sí òdodo. Nípa ìnà rẹ̀ ni ẹ fi ní ìmúláradá.

Peteru Kinni 2

Peteru Kinni 2:20-25