Peteru Keji 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ̀, à ń dúró de àwọn ọ̀run titun ati ayé titun níbi tí òdodo yóo máa wà.

Peteru Keji 3

Peteru Keji 3:7-17