Peteru Keji 3:12 BIBELI MIMỌ (BM)

kí ẹ máa retí ọjọ́ Ọlọrun, kí ẹ máa ṣe akitiyan pé kí ó tètè dé. Ní ọjọ́ náà, àwọn ọ̀run yóo parun, gbogbo ẹ̀dá ojú ọ̀run yóo yọ́ ninu iná.

Peteru Keji 3

Peteru Keji 3:11-18