Peteru Keji 1:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ fi ìkóra-ẹni-níjàánu kún ìmọ̀, kí ẹ fi ìgboyà kún ìkóra-ẹni-níjàánu, kí ẹ sì fi ìfọkànsìn kún ìgboyà.

Peteru Keji 1

Peteru Keji 1:2-14