Peteru Keji 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí èyí, kí ẹ ní ìtara láti fi ìwà ọmọlúwàbí kún igbagbọ yín, kí ẹ sì fi ìmọ̀ kún ìwà ọmọlúwàbí.

Peteru Keji 1

Peteru Keji 1:4-10