Orin Solomoni 8:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ǹ bá sìn ọ́ wá sílé ìyá mi,ninu ìyẹ̀wù ẹni tí ó tọ́ mi,ǹ bá fún ọ ní waini dídùn mu,àní omi èso Pomegiranate mi.

Orin Solomoni 8

Orin Solomoni 8:1-8