Èmi ni mo ni ọgbà àjàrà tèmi,ìwọ Solomoni lè ní ẹgbẹrun ìwọ̀n owó fadaka,kí àwọn tí wọn yá ọgbà sì ní igba.