Solomoni ní ọgbà àjàrà kan,ní Baali Hamoni.Ó fi ọgbà náà fún àwọn tí wọn yá a,ó ní kí ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn mú ẹgbẹrun (1,000) ìwọ̀n owó fadaka wá,fún èso ọgbà rẹ̀.