Orin Solomoni 5:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ni olùfẹ́ tìrẹ fi dára ju ti àwọn yòókù lọ?Ìwọ arẹwà jùlọ láàrin àwọn obinrin?Kí ni olùfẹ́ rẹ fi dára ju ti àwọn yòókù lọ?Tí o fi ń kìlọ̀ fún wa bẹ́ẹ̀?

Orin Solomoni 5

Orin Solomoni 5:1-15