Orin Solomoni 5:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo rọ̀ yín, ẹ̀yin ọmọbinrin Jerusalẹmu,bí ẹ bá rí olùfẹ́ mi,ẹ bá mi sọ fún un pé:Àìsàn ìfẹ́ ń ṣe mí.

Orin Solomoni 5

Orin Solomoni 5:6-15