Orin Solomoni 5:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ti bọ́ra sílẹ̀,báwo ni mo ṣe lè tún múra?Mo ti fọ ẹsẹ̀ mi,báwo ni mo ṣe lè tún dọ̀tí rẹ̀?

Orin Solomoni 5

Orin Solomoni 5:1-10