Orin Solomoni 5:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo sùn ṣugbọn ọkàn mi kò sùn.Ẹ gbọ́! Olùfẹ́ mi ń kan ìlẹ̀kùn.Ṣílẹ̀kùn fún mi,arabinrin mi, olùfẹ́ mi,àdàbà mi, olùfẹ́ mi tí ó péye,nítorí pé, ìrì ti mú kí orí mi tutù,gbogbo irun mi ti rẹ, fún ìrì alẹ́.

Orin Solomoni 5

Orin Solomoni 5:1-5