Orin Solomoni 4:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọgbà tí ó ní orísun omi ni ọ́,kànga omi tútù,àní, odò tí ń ṣàn, láti òkè Lẹbanoni.

Orin Solomoni 4

Orin Solomoni 4:11-15