igi nadi ati Safironi, Kalamusi ati Sinamoni,pẹlu oríṣìíríṣìí igi turari,igi òjíá, ati ti aloe,ati àwọn ojúlówó turari tí òórùn wọn dára jùlọ.