Arabinrin mi dàbí ọgbà tí a ti ti ìlẹ̀kùn rẹ̀.Ọgbà tí a tì ni iyawo mi;àní orísun omi tí a tì ni ọ́.