Oyin ní ń kán ní ètè rẹ, iyawo mi,wàrà ati oyin wà lábẹ́ ahọ́n rẹ,òórùn dídùn aṣọ rẹ dàbí òórùn Lẹbanoni.