Orin Solomoni 2:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo gbọ́ ohùn olùfẹ́ mi, wò ó! Ó ń bọ̀,ó ń fò lórí àwọn òkè ńlá,ó sì ń bẹ́ lórí àwọn òkè kéékèèké.

Orin Solomoni 2

Orin Solomoni 2:5-11