Orin Solomoni 2:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo kìlọ̀ fun yín, ẹ̀yin ọmọbinrin Jerusalẹmu,ní orúkọ egbin, ati ti àgbọ̀nrín pé,ẹ kò gbọdọ̀ jí ìfẹ́ títí yóo fi wù ú láti jí.

Orin Solomoni 2

Orin Solomoni 2:2-14