Àdàbà mi, tí ó wà ninu pàlàpálá òkúta,ní ibi kọ́lọ́fín òkúta,jẹ́ kí n rójú rẹ, kí n gbọ́ ohùn rẹ,nítorí ohùn rẹ dùn, ojú rẹ sì dára.