Orin Solomoni 2:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn igi ọ̀pọ̀tọ́ tí ń so èso,àjàrà tí ń tanná,ìtànná wọn sì ń tú òórùn dídùn jáde.Dìde, olùfẹ́ mi, arẹwà mi,jẹ́ kí á máa lọ.

Orin Solomoni 2

Orin Solomoni 2:8-17