Orin Dafidi 96:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí inú ọ̀run ó dùn, sì jẹ́ kí ayé ó yọ̀;kí òkun ó hó, ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀.

Orin Dafidi 96

Orin Dafidi 96:1-13